Àgùtàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Àgùtàn
Flock of sheep.jpg
A research flock at U.S. Sheep Experiment Station near Dubois, Idaho
Ipò ìdasí
Ọ̀sìn
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Ìdílé:
Subfamily:
Ìbátan:
Irú:
O. aries
Ìfúnlórúkọ méjì
Ovis aries

Àwọn Àgùtàn (Ovis aries) jẹ́ àwọn ẹranko afọ́mọlọ̀mú tí wọ́n sì ma ń tún ónjẹ wọn pọ̀ jẹ lẹ́yìn tí wọ́n bá ti jẹun tán. Bákan náà ni wọ́n sì tún jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin tí wọ́n ma ń jẹ̀ kiri. Ẹ̀wẹ̀, wọ́n tún jẹ́ ẹran ọ̀sìn abẹ́lé.[1]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Amelinckx, Andrew (2017-12-22). "6 Fun Facts About Sheep You Might Not Know". Modern Farmer. Retrieved 2018-12-11.