Àgbánréré
Appearance
Àgbánréré | |
---|---|
A Black rhinoceros (Diceros bicornis) at the Saint Louis Zoo. | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Ìjọba: | Animalia (Àwọn ẹranko) |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ) |
Ìtò: | Perissodactyla |
Superfamily: | Rhinocerotoidea |
Ìdílé: | Àgbánréré Owen, 1845 |
Extant and subfossil genera | |
Ceratotherium | |
Rhinoceros range |
Àgbánréré ni ìkan nñú irú-ẹ̀dá márùún oníka-tóṣẹ́kù ẹlẹ́sẹ̀ pátákó tó wà láyé nínú ìdílé Irúẹ̀dá-Àgbánréré (Rhinocerotidae), àti àwọn irú-ẹ̀dá yìówù tó jọ wọ́n sùgbọ́n tí wọn kò sí láyé mọ́. Méjì nínú àwọn irú-èdà tó wà láyé wà ní Áfríkà, mẹ́ta sì wà ní Apágúúsù Asia.