Àgbẹ̀
Ìrísí
Àgbẹ̀ ni ènìyàn tí ó ní oko tí ó fi ń ṣe iṣẹ́ ohun ọ̀gbìn jíjẹ láti inú ilẹ̀ tàbí ohun ọ̀sìn. Àgbẹ̀ tún jẹ́ ẹni tí ó ń là kàkà láti rí sí ìlọsíwájú oko rẹ̀ yálà nípa fífi owó, agbára àti ìfọkàntẹ̀ lórí àbájáde tó yanrantí fún èrè oko tó dára fún ìlò ọmọnìyàn. Àgbẹ̀ lè jẹ́ ẹni tí ó ń ni ilẹ̀ tí ó tún fi ń ṣe ohun ọ̀gbìn tàbí òsìn, ó sì tún lè jẹ́ ẹni tí ó yá ilẹ̀ tí ó ń san owó fún kí ó lè fi ṣe ohun ọ̀gbìn tàbí ohun ọ̀sìn fún ìlò ọmọnìyàn. [1] Àgbẹ̀ tún lè jẹ́ ẹni tí ó jẹ́ alágbàṣe tí olóko gbà láti báa ṣiṣẹ́ tí yóò sì sanwó ọ̀yà fún un. Ẹgbẹlẹmùkú ènìyàn pàá pàá jùlọ àwọn obìnrin ni wọ́n ń kópa nínú ìṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n sì ń pèsè ohun jíjẹ tàbí lílò fún ìlò ọmọnìyàn jákè-jádò agbáyé.[2][3] [4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Dyer 2007, p. 1: "The word 'farmer' was originally used to describe a tenant paying a leasehold rent (a farm), often for holding a lord's manorial demesne. The use of the word was eventually extended to mean any tenant or owner of a large holding, though when Gregory King estimated that there were 150,000 farmers in the late seventeenth century he evidently defined them by their tenures, as freeholders were counted separately."
- ↑ "Operating model – ifad.org". www.ifad.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2013-05-05. Retrieved 2018-01-02. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ HLPE, Committee on World Food Security ,Rome (June 2013). "Investing in smallholder agriculture" (PDF). fao.org. Retrieved 23 February 2021.
- ↑ "SOFA 2017 - The State of Food and Agriculture". www.fao.org. Retrieved 2021-03-08.