Àrùn ọpọlọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àrùn Ọpọlọ(tí a ma ùn pe ni "Stroki") jẹ ipo ibajẹ si ọpọlọ to o ma ún selè nitori idilọwọ ipese ẹjẹ (o le jé idinku gidigidi si èjè tó lo si opolo tabi idaduro patapata). Àrùn opolo ma ún yori si ailera awọn iṣan tabi ìropá rosè ni ẹgbẹ kan ara(ole jé apá òtún tàbí ti osi)

Ó jé àrùn asiwaju keta to un fa ikú ni àgbáyé [1]

Àwon Okùnfà Ewu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Isanraju

• Ojọ ogbó

• Otí mímu àpòjù

Ònà Àti Dènà Àrùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

• Yera fún àjejù iyò [2]

•Idaraya [3]

• yago fun sign [2]

Àwon Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

[1] [1] [2] [2] [3] [3]

  1. Ekeh, Bertha; Ogunniyi, Adesola; Isamade, Emmanuel; Ekrikpo, Udeme (2021-06-02). "Stroke mortality and its predictors in a Nigerian teaching hospital". African Health Sciences 15 (1). doi:10.4314/ahs.v15i1.10. PMID 25834533. https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pmc/articles/PMC4370132/. Retrieved 2022-02-02. 
  2. "7 things you can do to prevent a stroke". Harvard Health. 2013-06-01. Retrieved 2022-02-02. 
  3. "What Can Help Prevent a Stroke?". WebMD. Retrieved 2022-02-02.