Àtojo àwon ìjoba ìbílè ní ìpínlè Èkó nípa bí ènìyàn se pò sí
Ìrísí
Ìpínlẹ̀ Èkó ni agbègbè ìṣakoso marun, èyíinì ni, Ikorodu, Ikeja, Epe, Badagry, àti Lagos Island, tí Ikeja sì jẹ́ olú ìlú ìpínlè Èkó. Awọn agbègbè isakoso àti idagbasoke marun yi ni apapọ ní awọn agbegbe ijọba ibilẹ ogun (20) ati Awọn agbegbe isakoso (metadinlogoji)37 (LCDAs).
Àwon agbègbè isakoso ati idagbasoke yi ni Agbado/Oke-Odo, Agboyi-Ketu, Ayobo-Ipaja, Bariga, Egbe-Idimu, Ejigbo, Igando-Ikotun, Ikosi-Isheri, Isolo, Mosan-Okunola, Odi Olowo-Ojuwoye, Ojodu, Ojokoro, Onigbongbo and Orile Agege.
Ipo | LGA | Olugbe |
---|---|---|
1 | Alimosho | 11.456.783 |
2 | Ajeromi-Ifelodun | 2,000,346 |
3 | Kosofe | 665,421 |
4 | Mushin | 633.543 |
5 | Oshodi-Isolo | 1.621.789 |
6 | Ojo | 598,336 |
7 | Ikorodu | 535,811 |
8 | Surulere | 504,409 |
9 | Agege | 461.123 |
10 | Ifako-Ijaiye | 428,812 |
11 | Somolu | 402,992 |
12 | Amuwo-Odofin | 318.576 |
13 | Lagos oluile | 317,980 |
14 | Ikeja | 313.333 |
15 | Eti-Osa | 287,958 |
16 | Badagry | 241.437 |
17 | Apapa | 217.661 |
18 | Lagos Island | 209.665 |
19 | Epe | 181.715 |
20 | Ibeju-Lekki | 117.542 |