Àwọn Òpó Márùún Ìmàle
Ìrísí
Ìkan nínú àwọn àyọkà lórí |
Ìmàle |
Ìgbàgbọ́ |
---|
Allah · Ọ̀kanlọ̀kan Ọlọ́run · Àwọn Ànábì · Revealed books · Àwọn Mọ̀láíkà |
Àwọn ojúṣe |
Àwẹ̀ · Ìṣọrẹ · Ìrìnàjò |
Ìwé àti òfin |
Fiqh · Sharia · Kalam · Sufism |
Ìtàn àti olórí |
Timeline · Spread of Islam Imamate |
Àṣà àti àwùjọ |
Academics · Animals · Art Mọ́ṣálásí · Ìmòye Sáyẹ́nsì · Àwọn obìnrin Ìṣèlú · Dawah |
Ẹ̀sìn ìmàle àti àwọn ẹ̀sìn yìókù |
Hinduism · Sikhism · Jainism · Mormonism |
Ẹ tún wo |
Glossary of Islamic terms |
Èbúté Ìmàle |
Àwọn Òpó Márùún Islam (Arabic: أركان الإسلام) ni à ń pè àwọn ojúṣe márùn-ún tó ṣe dandan fún Mùsùlùmí. Àwọn ojúṣe wọ̀nyí ni:
- Shahada (ìjẹ́rìísí ìgbàgbọ́ wí pé ọ̀kan ṣoṣo ni Ọlọ́run àti pé ànọ́bì muhammad ẹrúsìn àti òjíṣẹ rẹ̀ ní ń ṣe),
- Irun (àdúrà ojoojúmọ́ fún àwọn àdáyanrí wákàtí márùn-ún),
- Ìtọrẹ àánú Zakat jẹ ọ̀ranyàn lẹ́ẹ̀kan lọ́dún fún gbogbo Mùsùlùmí tí ó bá ní owó ní ìpamọ́ ká odindin ọdún tí bùkátà kan kò kọlù. Ìdá kan nínú ogójì ni yóò fi ta ọrẹ (ọ̀pọ̀lọpọ̀ Mùsùlùmí ma ń sábà yọ zakat wọn lóṣù Ramadan nítorí i ládá tó pọ̀ nínú oṣù náà)
- Àwẹ̀ oṣù Ramadan jẹ́ àwẹ̀ ọ̀ràn yàn ní gbígbà nínú oṣù Ramadan fún gbogbo Mùsùlùmí, àti
- Haji (ìrìn-àjò lọ sí Mekka, ibi tí Masjid al-Haram (MỌṣáláṣí Mímọ́) wà, tó jẹ́ mosalasi tó gbajúmọ̀ jùlọ nínú Ìmàle).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |