Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi ile Naijiria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ile Naijiria ni Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi to po

Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Isinmi
Deeti Awon Akiyesi
New Year's Day 1 January Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi Ìbẹ̀rẹ̀ Ọdún tuntun.
Women's Day 8 March Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi láti fi bí àwọn Obìnrin ṣe ń kópa láwùjọ wọn jákè jádò àgbáyé.
Workers' Day 1 May Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi fún awon Osise jákè jádò àgbáyé.
Children's Day 27 May Àyájọ́ ọjọ ìsinmi fún àwọn ògo wẹẹrẹ.
Democracy Day 29 May Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi fún isejoba awa arawa ni orile ed Niajiria.
Independence Day 1 October Commemorates the Independence of Nigeria from Britain.
Christmas Day 25 December Christian holiday commemorating the birth of Jesus.
Boxing Day 26 December Christian holiday commemorating the day after Christmas.

Àwọn àyájọ ọjọ́ ìsinmi tó ma ń yí padà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lafikun, orile ede Naijiri ni awon ayajo ojo isinmi kan ti deeti won ma n yi lodoodun:

Ìsinmi Àwọn Àkíèsí
Mawlid Ayajo ojo isinmi awon Musulumi, ni iranti ojo ibi  Anobi Muhammad.
Eid al-Adha Ayajo ojo isinmi awon Musulumi, ni iranti igbafa ojise Olorun Ibrahim lati finu findo fomo re rubo fOlorun Oba.
Eid al-Fitr Ayajo ojo isinmi awon Musulumi, fun sisajoyo ipari Osu Awe Ramadan.
Good Friday Ayajo ojo isinmi awon omo leyin Kirisiti fun iranti kikan Jesus mo agbelebu.
Easter Monday Ayajo ojo isinmi awon leyin Kirisiti fun iranti ojo Ajinde Jesu

Àwọn ìtọka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]