Àwọn olórí ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà

1st October, 1979 (Ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá 1979) General Olúṣégun Ọbásunjọ́ fi ọ̀pá àṣẹ lé Alhaji Shehu Shagari lọ́wọ́.

26th August 1993: (Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́jọ 1993) General I.B. Babangida yẹ̀bá fún Chief Earnest Shónẹ́kan. Olórí ogun tí ó jẹ́ àrẹ ni Bàbángida náà pe ara rẹ.

9th June 1998: (Ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 1998) General Abdusalami Abubakar ni wọ́n yàn láti rọ́pò General Sani Abacha.

29th May 1999: (Ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1999). General Abdusalami Abubakar gbé ìjọba fún Chief Olúsẹ́gun Ọbásanjọ́.

29th May 2007: (Ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2006) Chief Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ gbé ìjọba fún Alhaji Umaru Yar’Adua.