Èbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyí/Kókó orí
Appearance
- Ìjàmbá ìtúká olóró ṣẹlẹ̀ ní Bèírùtù, Lẹ́bánọ́nù. Ó fikú pa àwọn ènìyàn tó tó 171.
- John Lewis ọmọ ọdún 80, alákitiyan àti olóṣèlú ará Amẹ́ríkà ṣe aláìsí ní ìlú Atlanta, USA.
- Ààrẹ ilẹ̀ Bùrúndì, Pierre Nkurunziza (fọ́tò) ṣe aláìsí ní Bùrúndì.
- Bàálù agbérò ti Pakistan International Airlines jálulẹ̀ nítòsí Karachi, ó ṣe ikú pa àwọn ènìyàn àádôrun lé méje.
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |