Èdè Azerbaijani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Azerbaijani
Azərbaycan dili (Latin script)
Азәрбајҹан дили (Cyrillic script)
آذربایجان دیلی (Perso-Arabic script)
Ìpè /azærbajdʒan dili/
Sísọ ní  Iran,
 Azerbaijan
 Georgia,
 Jẹ́mánì
 Russia,
 Estonia
 UK
 USA
 Uzbekistan
 Syria
 Iraq[1],
 Turkey,
 Turkmenistan
 Ukraine,
 Canada
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀

20-31 million [2][3][4][5][6]

[7]
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọ Latin alphabet for North Azeri in Azerbaijan, Perso-Arabic script for South Azeri in Iran, and, formerly, Cyrillic alphabet for North Azeri (Azerbaijani variants)
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́ Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 az
ISO 639-2 aze
ISO 639-3 variously:
aze – Azerbaijani (generic)
azj – North Azerbaijani
azb – South Azerbaijani
[[File:
Idioma azerí.png

Map showing locations of Azeri
|300px]]

Èdè Azerbaijani

Omo egbé ni èdè yìí jé fún egbé èdè tí a ń pè ní Turkic. Egbé èdè Turkic yìí jé omo ebí Altaic. Àwon tí ó ń so Azerbaijani tó mílíònù mérìnlá ní Azerbaijan ní ibi tí wón ti ń lò ó gégé bí èdè ìse ìjobi. Wón tún ń so èdè yìí ní Turkey, Syria àti Afgloanistan. Wón tún máa ń pe èdè yìí ni Azeri. Àkotó Cyrillic ni wón fi ń ko ó sílè ní Azerbaijan sùgbón àkotó Arabic ni wón fi ń ko ó sílè ní Iran. Wón fi ojú èdá èdè pín won sí Swuthern Azerbaijani) àti Northern Azerbaijani tí mílíònù méje ènìyàn ń so.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ethnologue
  2. "Peoples of Iran" in Looklex Encyclopedia of the Orient. Retrieved on 22 January 2009.
  3. http://www.terrorfreetomorrow.org/upimagestft/TFT%20Iran%20Survey%20Report%200609.pdf
  4. "Iran: People", CIA: The World Factbook: 24% of Iran's total population. Retrieved on 22 January 2009.
  5. G. Riaux, "The Formative Years of Azerbaijani Nationalism in Post-Revolutionary Iran", Central Asian Survey, 27(1): 45-58, March 2008: 25% of Iran's total population (p. 46). Retrieved on 22 January 2009.
  6. "Iran", Amnesty International report on Iran and Azerbaijanis . Retrieved 30 July 2006.
  7. Ethnologue total for South Azerbaijani plus Ethnologue total for North Azerbaijani
  8. "[1] Ethnologue"