Azerbaijan
Ìrísí
Orile ede Aserbaijan Azərbaycan Respublikası
| |
---|---|
Motto: none | |
Orin ìyìn: Azərbaycan Respublikasının Dövlət Himni (March of Azerbaijan) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Baku |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Èdè Aserbaijani |
Orúkọ aráàlú | Azerbaijani |
Ìjọba | Presidential republic |
• Aare | Ilham Aliyev (İlham Əliyev) |
Mehriban Aliyeva (Mehriban Əliyeva) | |
Ali Asadov (Əli Əsədov) | |
Olominira from the Soviet Union | |
• Declared | August 30 1991 |
• Completed | October 18 1991 |
Ìtóbi | |
• Total | 86,600 km2 (33,400 sq mi) (114th) |
• Omi (%) | 1.6% |
Alábùgbé | |
• 2018 estimate | 9,937,448[1] (91th) |
• 2002 census | 8,265,000 |
• Ìdìmọ́ra | 113/km2 (292.7/sq mi) (99th) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $94.318 billion[2] (77th) |
• Per capita | $10.340[2] (96th) |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $72.189 billion[2] (85th) |
• Per capita | $7,914[2] (78th) |
Gini (2006) | 36.5 medium · 58th |
HDI (2007) | ▲ 0.746 Error: Invalid HDI value · 98th |
Owóníná | Manat (AZN) |
Ibi àkókò | UTC+4 |
Àmì tẹlifóònù | 994 |
Internet TLD | .az |
Aserbaijan Ní ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ́ mílíọ̀nù méjè àbọ̀. Òun ni ó jẹ́ èdè ìjọba fún Aserbaijani níbi tí àwọn ìdá mẹ́ta nínú mẹ́rin àwọn tí ó ń gbé ibẹ̀ ti ń sọ ọ́. Àwọn ìdá mẹ́fà nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé Rọ́sía ni ó ń sọ èdè yìí. Àwọn èdè bú méjìlà mìíràn tún wà èyí tí Avar àti Armerican wà lára wọn.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Azerbaijan Population (1950 - 2018) -
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 "Azerbaijan:Report for Selected Countries and Subjects". International Monetary Fund. Retrieved April 12, 2011.