Báháráìnì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Kingdom of Bahrain
مملكة البحرين
Mamlakat al-Baḥrayn
Àsìá
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèبحريننا
Bahrainona
Our Bahrain
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Manama
26°13′N 50°35′E / 26.217°N 50.583°E / 26.217; 50.583
Èdè oníbiṣẹ́ Arabic [1]
Orúkọ aráàlú Ará Bahrain
Ìjọba Constitutional Monarchy
 -  King Hamad bin Isa Al Khalifah
 -  Queen Sabika bint Ibrahim
 -  Prime Minister Khalifah ibn Sulman Al Khalifah
Independence
 -  From Portugal 1602 
 -  From Persia 1783[2][3] 
 -  From United Kingdom December 16, 1971[4] 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 750 km2 (184th)
290 sq mi 
 -  Omi (%) 0
Alábùgbé
 -  Ìdíye  791,000[5] (159th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 1,189.5/km2 (7th)
3,126.5/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $27.014 billion[6] (118th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $34,662[6] (32nd)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $21.236 billion[6] (96th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $27,248[6] (3rd)
HDI (2007) 0.895[7] (high) (39th)
Owóníná Bahraini dinar (BHD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC+3)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .bh
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 973

Bahrain tabi Ile-Oba Bahrain Ní odún 1995, àwon ènìyàn tí ó ń gbé orílè-èdè yìí tó egbèrún lónà èédégbèta àti ààbò (555,000). Èdè Lárúbááwá (Arabic) ni èdè ìjoba ní ibè. Àwon èdè kan tún wà tí wón ń so níbè. Àwon èdè náà ni fáàsì (farsi) tí àwon tí ó ń so ó egbèrún méjìdínláàádóta (48, 000); Úúdù (Urdu) tí àwon tí ó ń so ó tó egbèrún lónà ogún (20,000) àti àwon èdè fílípíìnì (Phillipine) mìíràn tí àwon tí ó ń so wón tó egbèrún lónà ogún (20,000). Èdè Gèésì ti ń gbayì ní ilè yìí sí i gégé bí èdè òwò àti èdè ìse àbèwò sí ìlú (tourism).
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Article 2(The official language is Arabic.)
  2. CIA World Factbook, "Bahrain"
  3. " Bahrain ." Encyclopædia Britannica. 2008. Encyclopædia Britannica Online. 16 2008 [1]
  4. Àṣìṣe
  5. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 "Bahrain". International Monetary Fund. http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2009/02/weodata/weorept.aspx?sy=2006&ey=2009&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=419&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=19&pr.y=5. Retrieved 2009-10-01. 
  7. "Human Development Report 2009: Bahrain". The United Nations. http://hdrstats.undp.org/en/countries/country_fact_sheets/cty_fs_BHR.html. Retrieved 2009-10-18.