Jump to content

Èdè Balanta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Balanta
Sísọ ní(Balanta-Kentohe) Guinea-Bissau, (Balanta-Ganja) the Gambia, Senegal
Ọjọ́ ìdásílẹ̀2006
Ẹ̀yàBalanta
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀510,000
Èdè ìbátan
Èdè ajẹ́kékeré ní Senegal
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3either:
ble – Balanta-Kentohe
bjt – Balanta-Ganja

Balanta (tàbí Balant) jẹ́ àwọn èdè Bak méjì tí ó jọra tí àwọn ènìyàn Balanta ń sọ.

À le pín èdè Balanta sí méjì: Balanta-Kentohe àti Balanta-Ganja.[1][2]

Àwọn ènìyàn tí ó tó 423,000 ní iye ni ó ń sọ èdè Balanta-Kentohe (Kəntɔhɛ) ní orílè-èdè Guinea-Bissau (ní ọdún 2006, àwọn tí ó ń sọ èdè náà tó 397,000, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn sì ló wà ní Agbègbè Oio[3]) àti ní Gámbíà. Wọ́n ti ṣàgbéjáde àwọn fíìmù àti àwọn apá Bíbélì kan ní èdè Balanta-Kentohe.

The Kəntɔhɛ dialect is spoken in the north, while the Fora dialect is spoken in the south.[4]

Ethnologue lists the alternative names of Balanta-Kentohe as Alante, Balanda, Balant, Balanta, Balante, Ballante, Belante, Brassa, Bulanda, Frase, Fora, Kantohe (Kentohe, Queuthoe), Naga and Mane. The Naga, Mane and Kantohe dialects may be separate languages.

Àwọn tí ó sọ èdè Balanta-Ganja ní gúúsù àti gúúsù ìwọ oòrùn Senegal tó 86,000 ní iye (ní ọdún 2006). is less than 1% for Balanta-Ganja.[1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Balanta-Kentohe". Ethnologue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-06. 
  2. 2.0 2.1 "Balanta-Ganja". Ethnologue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-06. 
  3. "Balanta-Kentohe Language (ble)". The Rosetta Project. Archived from the original on 2011-07-27. Retrieved 2011-02-28. 
  4. Wilson, William A. A. (2007) (in en). Guinea Languages of the Atlantic Group: Description and Internal Classification. Schriften zur Afrikanistik, 12. Frankfurt am Main: Peter Lang.