Èdè Efe
Appearance
Ewe | |
---|---|
Eʋe, Eʋegbe | |
Sísọ ní | Ghana, Togo |
Agbègbè | Southern Ghana east of the Volta River, southern Togo |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | over 3 million, with 500,000 second language speakers |
Èdè ìbátan | |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | ee |
ISO 639-2 | ewe |
ISO 639-3 | ewe |
Èdè Efe tabi èdè Ewe (tabi efegbe) je ede Niger-Kongo ti won n lo ni Ghana, Togo ati Benin.
Èdè olóhùn ní èdè yìí orísìí àmì òhun merin ni wọn ń fi ń pe e. Ni abe Ẹbi Niger Congo ni èdè yìí wa.
Mílíọ̀nù mẹta ni iye àwọn tí ń sọ èdè yìí. (3 Million).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |