Jump to content

Èdè Tem

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tem
Kotokoli
Sísọ níTogo, Ghana, Benin, Burkina Faso
Ọjọ́ ìdásílẹ̀2012–2018
Ẹ̀yàTem people
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀Àdàkọ:Sigfig
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọLatin (Tem alphabet)
Tem Braille
Arabic (former)
Èdè ajẹ́kékeré ní Benin
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3kdh

Tem, tàbí Kotokoli (Cotocoli), jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Gur tí wọ́n ń sọ ní Togo, Ghana, Benin àti Burkina Faso. Ó tún jẹ́ èdè tí àwọn kọ̀kan ní àyíká orílẹ̀ èdè yí ń sọ. Ní Ghana, àwọn ènìyàn Kotokoli wá láti àríwá agbègbè Volta ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Koue. Koue pín àlà pẹ̀lú Togo, odò kékeré(odò Koue) sì ló wà láàrin Koue àti Togo.

Yàtò sí ilè abínibí wọn, àwọn Tem/Kotokoli yapa káàkiri àwọn ibi ní orílẹ̀-èdè Ghana. Wọ́n pọ̀ ní àwọn agbègbè bi Nima-Mamobi, Madina, Dodowa, Asaman, Jamasi, Aboaso àti àwọn agbègbè míràn. Orúkọ olóyè wọn ní Wuro, òun sì ni olórí ilẹ̀ Koue.

Álífábẹ́tì wọn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Álífábẹ́tì
Uppercase A B C D Ɖ E Ɛ F G Gb H I Ɩ J K Kp L M N Ny Ŋ Ŋm O Ɔ P R S T U Ʊ V W Y Z
Lowercase a b c d ɖ e ɛ f g gb h i ɩ j k kp l m n ny ŋ ŋm o ɔ p r s t u ʊ v w y z