Jump to content

Ìjẹ́ẹ̀rí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Shahada tabi ìjẹ́ẹ̀rí (Arabic: الشهادة aš-šahāda as-shahadah.ogg audio ) (lati oro-ise [] error: {{lang}}: no text (help) šahida, "o jeri"), tumo si "lati mo ati gbagbo laisi ifura, bi jijeri"; o je ikan ninu awon opo marun islam. Shahada ni ike igbagbo ninu okan Allahu ta'âlâ ati igba Muhammad gege bi ojise Olorun. Ike yi ni pe:

lâ ilâha illallâh, Muḥammadur rasûlullâh (ni Larubawa)
Ko si olorun miran afi Olorun, Muhammad si ni Ojise Olorun (ni Yoruba)