Jump to content

Ìjọba àìlólórí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìjọba àìlólórí (Anarchy, ἀναρχίᾱ anarchíā) le je ikan ninu iwonyi:

  • "Ko si olori tabi alase kankan."[1]
  • Aisi ijoba; ailofin nitori aisi ijoba kankan to le gbofin ro.[2]
  • Awujo to je pe ko si eni kankan ni ipo ijoba, sugbon ti olukaluku ni ominira patapata (laisi modaru).[3]


  1. Decentralism: Where It Came From--Where Is It Going?
  2. "anarchy." Oxford English Dictionary. Oxford University Press. 2004. The first quoted usage is 1552
  3. "anarchy." Oxford English Dictionary. Oxford University Press. 2004. The first quoted usage is 1850.