Jump to content

Ìlù Bàtá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìlù Bàtá gẹ́gẹ́ bí ìlú olójú-méjì

Àdàkọ:Infobox instrument

Ìlù Bàtà jẹ ìlù kan ti o ni oju meji, ikan ni iwaju ikan lẹyin. Amọ, oju ilu ti o wa ni iwaju fẹ̀ ju ti ẹ̀yìn lọ. Ọdun ibilẹ, ọdun òrìṣà Sàngó, ilu SanteríaCuba láti ọdún 1800s, àti ní Puerto Rico àti ni orílẹ̀-èdè Amẹríka láti ọdun 1950s.[1] ni a ma n lo ilu yi fun, bakan naa ni wọn tun ma n loo fun oriṣriṣi ayẹyẹ ni ile Yorùbá.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Corrales, Mark (July 28, 2004). "The Bata Drums". Reprinted by World Music Central. Original article published by the Latin American Folk Institute (LAFI) of Washington DC. Archived from the original on 30 January 2021. Retrieved January 10, 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)