Ìpín Àgbádárìgì (Badagry)
Ìrísí
Ìpín Àgbádárìgì ni ìpín kan lára ẹ̀ka tí ọ́ ń ṣe àkóso ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ìtàn rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpín Àgbádárìgì kópa tó lọ́ọrìn nígbà tí a bá ń ṣe àgbéyẹ̀wò nínú ìtàn ilẹ̀ Olómìnira Nàìjíríà àti Europe. Gẹ́gẹ́ bí Àgbádárìgì ṣe jẹ́ agbègbè tí wọ́n ti kó ẹrú tí ó pọ̀ jùlọ nínú iṣẹ́ Òwò Ẹrú lágbàáyé, ṣáájú ìjẹ gàba àwọn Èèbó Amúnisìn. Ìpín Àgbádárìgì tún jẹ́ ibi tí àwọn Èèbó Aláwọ̀ fundun ti kọ́kọ́ polongo ẹ̀sìn Krístẹ́nì ní ikẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1842. Wọ́n kọ́ ilé alágbèékà síbẹ̀ láti fi ṣebìrántí Agia Cenotaph.[1]
Àwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpín Àgbádárìgì ní Ìjọba Ìbílẹ̀ mẹ́rin :[2]
Àwọn Ìletò tó yi ká
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Badagry
- Ìlú àrẹ́ko Àgbò
- Òkè oko
- Àjárá
- Ìwóró-Àjìdò
- Àkarakúmọ́
- Gbàjí
- Àṣerí
- Ẹgàn
- Aganrin
- Ahanfe
- Ẹ̀pẹ́
- Posí
- Mowó
- Ìtọ́ga
- Ebiri
- Ekunpa
- Àràdàgún
- Bèrèkéte
- Mosáfẹ́jọ
- Gayingbo-Tọpó
- Kànkon Moba
- Popojí
- Oranyan
- Tafí- Àwórì
- Yeketome
- Ipóta
- Sẹ̀mẹ̀ Border
- Ìyáfin
- Farasime
- Mushin
Àwọn Ẹ̀ka Àqórì :
- Àwòdì -Ọrà
- Ìsaṣì
- Ọ̀tọ̀- Àwórì-
- Ìjànikin
- Ilogbò
- Oko-Afọ́
- Ṣìbírí
- Àpá
- Ìdí-Olúwò
- Ado-Soba
- Ìbèṣè
- Ìréde
- Irese
- Mèbámù
- Itewe
- Igede
- Àjàngbàdì
- lyagbe
- Ajégúnlẹ̀
- Ayétòrò
- Festac Town
- Satellite Town
- Ibà
- Kiríkirì
- Agbójú-Àmúwó
- Òkòmaikò
- Ọ̀jọ́
- Amúkokò
- Alábà-Ore
- Ìjọ̀yìn
- Ìgbànkọ̀
- Ìmọ́rẹ́
- Ìjegun
- Mushin
- Ìsọlọ̀
- Ọ̀tà
- Ilẹ́mbà-Àwórì
- Ìtìrẹ́
- Ìpájà
- Agége
- Ìbẹ̀rẹ́ko
Ibi tí kò gbajúmọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Eko University of Medicine and Health Sciences ni ó wà ní Ìpín Àgbádárìgì.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lagos State Website Archived 2008-02-15 at the Wayback Machine.
- ↑ User, Super (2016-04-06). "Lagos State". Nigeria. Archived from the original on 2019-10-24. Retrieved 2019-10-27.
- ↑ Bassey, Ben (2018-02-11). "APC Badagry division seeks second term for Governor". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-10-27.
- ↑ Ventures, Kaiste. "Training in Badagry Division, Lagos State, Nigeria -". Nigerian Seminars and Trainings. Retrieved 2019-10-27.