Ọ̀rànmíyàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Ninu itan aroso enu ile Yorùbá Oranmiyan tabi Oranyan je Oba lati Ile-Ife be ni o tun je omo Oduduwa. Ohun ni itan aroso enu yi so wipe o da ilu Oyo sile.