Ìpínlẹ̀ Mississippi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ipinle Mississippi
Flag of Mississippi State seal of Mississippi
Flag of Mississippi Èdìdí
Ìlàjẹ́: The Magnolia State, The Hospitality State
Motto(s): 'Virtute et armis (By Valor and Arms)
[[File:|center|alt|Map of the United States with Mississippi highlighted|270px]]
Èdè oníibiṣẹ́ English
Orúkọaráàlú Mississippian
Olúìlú Jackson
Ìlú atóbijùlọ Jackson
Largest metro area Jackson metropolitan area
Àlà  Ipò 32nd ní U.S.
 - Total 48,434 sq mi
(125,443 km2)
 - Width 170 miles (275 km)
 - Length 340 miles (545 km)
 - % water 3
 - Latitude 30° 12′ N to 35° N
 - Longitude 88° 06′ W to 91° 39′ W
Iyeèrò  Ipò 31st ní U.S.
 - Total 2,910,540
Density 60.7/sq mi  (23.42/km2)
Ranked 32nd in the U.S.
Elevation  
 - Highest point Woodall Mountain[1]
806 ft (246 m)
 - Mean 300 ft  (91 m)
 - Lowest point Gulf of Mexico[1]
sea level
Admission to Union  December 10, 1817 (20th)
Gómìnà Phil Bryant (R)
Ìgbákejì Gómìnà {{{Lieutenant Governor}}}
Legislature {{{Legislature}}}
 - Upper house {{{Upperhouse}}}
 - Lower house {{{Lowerhouse}}}
U.S. Senators Cindy Hyde-Smith (R)
Roger Wicker (R)
U.S. House delegation List
Time zone Central: UTC-6/-5
Abbreviations MS Miss. US-MS
Website mississippi.gov

Mississippi Ipinle kan ni ile Amerika ni o n je Mississippi. Awon eniyan ti o wa nibe to 2,217,000. Olu-ilu ibe ni Jackson. Awon ara Panyan-an wa si ile yii ni 1540. Awon ara Faranse wa do si ibe 1699. Awon ara Geesi segun awon Faranse ni 1763. Ni odun 1817 ni Mississippi dara po mo Union. Awon eru po ni ibe o si ni opolopo plantation. O duro ti awon Confederate ninu ioja abele ile Amerika. Odo kan wa ni ipinle yii ti o n je Mississippi. Odo yii ni o gun nju ni ile Amerika. Ti a ba pa odo yii ati Missouri po, awon ni o gun ju ni gbogbo aye. Mississippi gun to maili 2,350.. Oun ati Missouri gun to 3,700 ni ibuso. Odun 1541 ni won se awari Mississippi ni Memphis, Tennessee. Omo ile Panyan-an ti o se awari re ni won n pe ni Hernando de Soto.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Elevations and Distances in the United States". U.S Geological Survey. 29 April 2005. Archived from the original on 2008-06-01. Retrieved November 6.  Unknown parameter |accessyear= ignored (|access-date= suggested) (help); Check date values in: |access-date=, |date= (help)