Ìròyìn Oṣù Keje 2011
Ìrísí
- Malangatana, akun àwòrán ará Mozambique kú ní Pọ́rtúgàl.
- Dilma Rousseff di obìnrin àkọ́kọ́ Ààrẹ 36k orílẹ̀-èdè Brasil.
- Àgbàrá fàá kí àwọn ènìyàn 200,000 ó fi ibùgbé wọn sílẹ ní ìpínlẹ̀ Queensland ní Australia.
- Lẹ́yìn ìbòaráàlú tó ti wáyé, Gúúsù Sudan (àsìá), yapa kúrọ̀ lọ́dọ̀ Sudan láti di orílẹ̀-èdè olómìnira.
- Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis gbérá láti Kennedy Space Center fún ìfòlókè STS-135 tó jẹ́ ìránlọṣe tó parí ètò Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú.
- Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Káríayé kéde pé Pyeongchang, Gúúsù Kòréà, ni yíò gbàlejò Òlímpíkì Igbà Ọyẹ́ 2018.
- Alákóso Agba Lebanon Najib Mikati dá ìjọba tuntun.
- Rálì Dàkár 2011 wá só pin ní Buenos Aires.
- Ààrẹ Zine El Abidine Ben Ali sá kúrò ní Tunisia lẹ́yìn jàgídíjàgan tó ṣẹlẹ̀ káàkiri orílẹ̀-èdè; Fouad Mebazaa di adípò Ààrẹ.