Ìyanya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

'Àdàkọ:EngvarB

Iyanya
Iyanya in 2013
Iyanya in 2013
Background information
Orúkọ àbísọIyanya Onoyom Mbuka
Ọjọ́ìbí31 Oṣù Kẹ̀wá 1986 (1986-10-31) (ọmọ ọdún 37)[1]
Calabar, Cross River State, Nigeria
Irú orinAfropop, R&B
Occupation(s)Singer
Years active2008–present
LabelsTemple Music Group, Mavin, Made Men Music Group

Ọjọ́ kankànlélọ́gbọ̀n, oṣù Ọ̀wàwà ní wọ́n bí Iyanya Onoyom Mbuk, tí orúkọ ìtàgẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ Iyanya. Olórin tàka-súfèé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Ìyanya. Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká nígbà tí ó gbégbá orókè nínú ìdíje Project Fame West Africa àti wí pé orin rẹ̀"Kukere" tún jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́.[2][3] Ó pawọ́pọ̀ dá ilé-iṣẹ́ tí ń gbé ori jáde Made Men Music Group pẹ̀lú Ubi Franklin ní ọdún 2011. Ó ṣẹ àwo orin rẹ̀ My Story ní ọdún 2011. Lẹ́yì náà ni ó ṣẹ "No Time" àti "Love Truly". Nínú àwo rẹ̀ kejì Desire, orin márùn-ún ni ó wà ní bẹ̀ "Kukere", "Ur Waist", "Flavour", "Sexy Mama", and "Jombolo". Ó gba àmì-ẹ̀yẹ olórin tó dára jù ní The Headies 2013. Ní oṣù Ọ̀wàwà , ọdún 2016 ó kéde lórí ẹ̀rọ ayélujára Instagram òun ti ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Mavin Records.[4] Ní oṣù mẹ́ta kó tó di ìgbà yẹn, ó tọwọ́ bọ ìwé láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Temple Management Company.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "CHARITABLE: Iyanya Celebrates Birthday With Inmates At Ikoyi Prisoner (Photos)". 360nobs. Retrieved 21 December 2013. 
  2. "Celebrity Focus: Iyanya – The Many Flavours Stirring Controversies". Onobello. Archived from the original on 6 June 2013. Retrieved 30 July 2013. 
  3. "Iyanya, Artist Biography-MTV Base". Mtvbase. Retrieved 29 July 2013. 
  4. Augoye, Jayne (1 November 2016). "INTERVIEW: Why I signed for Mavin Records — Iyanya". Premium Times. Retrieved 7 January 2017. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. Vwovwe, Egbo (28 July 2016). "Iyanya Singer signs with Temple Management Company". Pulse. Archived from the original on 22 September 2017. Retrieved 21 September 2017.