Ẹ̀dè Lyélé
Ìrísí
Lyélé | |
---|---|
Lele | |
Sísọ ní | Burkina Faso |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | Àdàkọ:Sigfig |
Èdè ìbátan | |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | lee |
Èdè Lyélé language (Lele) jẹ́ èdè kan tí wọ́n ń sọ ní agbègbè Sanguié ní orílẹ̀ èdè Burkina Faso, àwọn tó ń sọ èdè náà tó ọ̀kẹ́ mẹ̀fà àbọ̀ (130,000), orúkọ tí wọ́n ń sì ń pe èdè yìí ni Lyéla, Léla, Gourounsi tàbí Gurunsi. Wọ́n ń só ní ìlú Réo, Kyon, Tenado, Dassa, Didyr, Godyr, Kordié, Pouni àti Zawara. Àwọn míràn tún ń pe èdè náà ní Gurunsi. Lyélé jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè SVO.
Àwọn lẹ́tà áfábẹ́tì wọn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]a | b | c | d | e | ə | ɛ | f | g | h | i | j | k | l | ly | m | n | ŋw | ny | o | p | r | rh | s | sh | t | u | v | w | y | z | zh |
Wọ́n ma ń lọ àwọn àmì sí ara Áfábẹ́tì Lyele láti fi ṣe Ìyàtọ̀ láàrin ọ̀rọ. Ohùn òkè àti ìsàlẹ̀ ní àmì ṣùgbọ́n ti àárín kò ní.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nikiema 1993, p. 50.