Ẹtu
Appearance
Ẹtu | |
---|---|
Blackbuck antelope of India | |
Scientific classification | |
Ìjọba: | Animalia (Àwọn ẹranko) |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ) |
Ìtò: | Oníka-dídọ́gba |
Infraorder: | Pecora |
Ìdílé: | Bovidae |
Groups included | |
Cladistically included but traditionally excluded taxa | |
Ẹtu ni à ún pe orísirísi àwọn ẹranko ajẹnu oníka-dídọ́gba tó jẹ́ abínibí sí orísi agbègbè ní Áfríkà àti Eurasia.