Ọ̀pá Ọ̀rànmíyàn
Ìrísí
Ọ̀pá Ọ̀rànmíyàn jẹ́ Ọ̀pá àṣẹ àti agbára tí Ọ̀rànmíyàn ń lò lójú ogun àti gẹ́gẹ́ bí ọba ìlú Ilé-Ifẹ̀ nígbà ayé rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí ìtàn àtẹnudẹ́nu, Ọ̀rànmíyàn jẹ́ Ọba alágbára Ilé-Ifẹ́. [1] [2] [3] Títí di òní yìí, Ọ̀pá Ọ̀rànmíyàn wà lára àwọn nǹkan ìṣèm̀báyé tí àwọn arìnrìn-àjò afẹ́ máa ń lọ wò ní Ilé-Ifẹ̀.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Oranmiyan staff". The Sun Nigeria. 2018-04-12. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "The restless children of Oranmiyan - The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2019-04-25. Archived from the original on 2019-11-23. Retrieved 2020-01-02.
- ↑ "Myths surrounding Oranmiyan Staff - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2015-10-16. Retrieved 2020-01-02.