Ọ̀rọ̀ oníṣe:Alaroye
Ẹkáàbọ̀!
Ẹpẹ̀lẹ́ o, Alaroye,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 06:46, 20 Oṣù Kọkànlá 2019 (UTC)
Ayoka tuntun
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Epele oo Alaroye,
Ti e ba fe ko ayoka tuntun, etele ilana yii
1. E wa akole ayoka ninu "Sawari ninu Wikipedia" search tab by your right hand) 2. Oju ewe tuntun yio so, to o ba ti so, e kiliki ayoka yii, oju ewe tuntun yio so fun yin Latin ko ayoka 3. Leyin eyi, e "kiliki satejade atunse"
English translation
To write a new article,
1. You will see a box at your right and side "S'awaari ninu Wikipedia", search for the tittle of the article in that box.
2. It will appear in red if there is no article about the title on Yoruba Wikipedia which means you can create it
3. Click on the redlink and create your article and when you are done 4. Save the page.
Tóbi Oyinlolá
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Tóbi oyinlolá (ojó ìbí:ojó kewàá osù Kaàrún odún 1992 ni ilú ìbàdàn,Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Nàìjíríà)
Omo bíbí orílè èdè Nàìjíríà tí ó jé onísòwò àti òjògbón. Ó lààmìlaaka lénu isé rè pèlú ilé-isé rloop incorporated, ilé-isé tí ó n gbìmò pò láti rii dájú pé àlá ìlanà ìrin àjò oní ìpele kaàrún ti Elon Musk se agbáterù rè wà sí ìmuse.[1] [2]
Tóbi Oyinlolá ni ó se agbáterù èro ònkà ìgbàlódé tí ó ma fún wa láàye láti San owó gáàsì ìdáná bí a sé n lòó. Èyí máa se àrídájú wípé àwon asàmúlò gáàsì ìdáná kò ní láti San owó gboboi lóríi gáàsì lékàn-an náà,tí ó sì jé pé owó ìwònba tí wón bá lò ni wón yíò San.[3]
Ògbéni Olúwatóbi se agbáterù irinsé tó dá sisé,pèlú ìtònsán Òrùn(Solar energy)fún ijó méta pèlú àjòsepò ìlú Kòréà Gúúsù,Amẹ́ríkà,àti Índíà.[4]
Ní Odún 2018,Wón dárúko rè pèlú àwon òdó mìíràn pèlú Davido gégébí àwon tí ó wúlò fún àwùjo.[5]
- ↑ "Oluwatobi Oyinlola". aficta.africa. Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "rLoop is the Latest Team Hellbent on Making Hyperloop a Reality". Autoevolution. Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "Pay-as-you-cook technology to boost use of affordable LPG in Rwanda". CNBCAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 September 2019.
- ↑ "Nigerian Tech Genius". Face2faceafrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "Most Influential Award". Pulse.NG. Retrieved 20 November 2019.