Abayomi Olonisakin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abayomi Gabriel Olonisakin
Ọ̀gá Ọmọṣẹ́ Ológun, Ọ̀gágun AG Olonisakin
Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
July 2015
AsíwájúACM. A.S Badeh
Commander, Training and Doctrine Command (TRADOC) Nigerian Army
In office
September 2013 – July 2015
AsíwájúMaj-Gen. S.Z. Uba
Commander, Nigerian Army Corps of Signals
In office
January 2013 – September 2013
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kejìlá 1961 (1961-12-02) (ọmọ ọdún 62)[1]
Ekiti state, Nigeria
Alma materNigeria Military School
Nigerian Defence Academy
Obafemi Awolowo University
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/service Jagunjagun Oríilẹ̀ Nàìjíríà
Years of service1979 -
RankGeneral
CommandsChief of Defence Staff
Commander, Training and Doctrine Command (TRADOC), Nigerian Army
Commander, Nigerian Army Corps of Signals

Abayomi Gabriel Olonisakin jẹ́ ọ̀gágun ní ilé-iṣẹ́ Jagunjagun orí-ilẹ̀ Nàìjíríà. Lọ́wọ́lọ́wọ́ Ọ̀gágun Olonisakin ni Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, Ààrẹ Muhammadu Buhari ló yàn sípò yìí ní ojọ́ 13 Osù Keje 2015.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Profile of the Chief of Defence Staff". Nigerian Defence Info (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-05-26. Retrieved 2020-04-05. 
  2. "Profiles of newly appointed service chiefs by Buhari". Vanguard Nigeria. Retrieved 18 July 2015.