Jump to content

Abdulla Baba Fatadi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdullah Baba Fatai
Personal information
OrúkọBabatunde Fatai-Baba Fatai
Ọjọ́ ìbí2 Oṣù Kọkànlá 1985 (1985-11-02) (ọmọ ọdún 39)
Ibi ọjọ́ibíLagos, Nigeria
Ìga1.76 m (5 ft 9 in)
Playing positionMidfielder[1]
Youth career
2000–2002Osaka Fc Lagos
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2002–2004Al Najma Club31(13)
2004–2006Al Ahli Club28(12)
2006–2008Muharraq Club30(14)
2008–2009Al-Kharitiyath S.C.23(2)
2009–2010Neuchâtel Xamax17(1)
2010–2011w:Ittihad Kalba10(0)
2011Al-Qadisiyah FC[2]10(1)
2011–2012Al Jahra19(3)
2012–2013Al-Shoalah11(0)
Al-Hidd
National team
2007–2012Bahrain46(8)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 1 August 2011.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 17 October 2011

Abdulla Baba Fatadi tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì Oṣù Kọkànlá ọdún 1985 (2nd November 1985) jẹ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Bahraini.[3] Ó jẹ́ olùdarí fún ẹgbẹ́ Al Jahra . Orukọ àbísọ rẹ̀ ni Babatunde Fatai. Ó gbá Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Naijirialábala àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ tí ọjọ́ orí wọ́n kò ju mẹ́tàdínlógún (17) lọ kí ó tó sọ ara rẹ̀ di ará orilẹ-èdè Bahrain lọ́dún 2004.

Awọn ifojusi fun ẹgbẹ orilẹ-ede giga

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
# Ọjọ Ibugbe Alatako O wole Esi Idije
21 Oṣu Kẹwa 2007 Manama , Bahrain Malaysia 4-1 Won FIFA Iwọn Agbaye FIFA 2010
16 January 2007 Manama , Bahrain   Kuwait 1-0 Won Ore
26 January 2008 Manama , Bahrain   Yemen 2-1 Won Ore
10 Kẹsán 2008 Doha , Qatar   Qatar 1-1 Fọ FIFA Iwọn Agbaye FIFA 2010
21 January 2009 Hong Kong , Hong Kong   ilu họngi kọngi 3-1 Won 2011 AFC Asian Cup qualification
23 Oṣù 2009 Manama , Bahrain   Zimbabwe 5-2 Won Ore
18 Kọkànlá Oṣù 2009 Manama , Bahrain   Yemen 4-0 Won 2011 AFC Asian Cup qualification
29 Kọkànlá Oṣù 2011 Aden , Yemen   Apapọ Arab Emirates 1-3 Isonu 2010 Gulf Cup of Nations
  1. "Abdulla Baba Fatadi Stats, News, Bio". ESPN. November 22, 2022. Retrieved November 22, 2022. 
  2. "Abdulla Baba Fatadi". worldfootball.net. November 2, 1985. Retrieved November 22, 2022. 
  3. Strack-Zimmermann, Benjamin (November 2, 1985). "Abdulla Baba Fatadi (Player)". National Football Teams. Retrieved November 22, 2022.