Jump to content

Abia Warriors F.C.

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abia Warriors F.C.
Founded2003
GroundUmuahia Township Stadium
(Capacity: 5,000)
OwnerAbia State Government
ChairmanEmeka Inyama[1]
ManagerEmmanuel Deutch
LeagueNigeria Professional Football League
2023-202412th
WebsiteClub home page
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Home colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Away colours

Abia Warriors Football Club jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá jẹun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n wà ní ìlú Umuahia, ní ìpínlẹ̀ Abia.

Lọ́dún 2005 sí ọdún 2010, "Orji Uzor Kalu FC" ni orúkọ tí wọ́n ń jẹ́. Wọ́n ṣe èyí láti bọlá fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia nígbà náà Orji Uzor Kalu fún ìrànlọ́wọ́ àti akitiyan rẹ̀ tí wọ́n fi gba ìgbéga sí ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Àgbábuta àgbà ti Nàìjíríà. Wọ́n padà sí orúkọ wọn àná lọ́dún 2010.[2]

Wọ́n ní ìgbéga sì ìdíje Agbábọ́ọ̀lù àgbà ti Nàìjíríà fún ìgbà àkọ́kọ́ lọ́dún 2013 lẹ́yìn tí wọ́n pegedé nínú ikọ̀ adíje Àgbábuta ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá kékeré.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]