Accident (fíìmù Nàìjíríà ní ọdún 2013)
Ìrísí
Accident | |
---|---|
Adarí | Teco Benson |
Olùgbékalẹ̀ | Teco Benson |
Àwọn òṣèré |
|
Orin | Austine Erowele |
Ìyàwòrán sinimá | Abdulahi Yusuf |
Olóòtú | Teco Benson |
Olùpín | TFP Global Network |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 91 minutes[1] |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English |
Accident jẹ́ eré orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ọdún 2013 tí Teco Benson gbé jáde tí ó sì darí rẹ̀ pẹ̀lú Kalu Ikeagwu àti Chioma Chukwuka gẹ́gẹ́ bí òṣèré tí ó kó ipa gbòógì.[2][3] Òun ni ó gba Best Nigerian Film award ní 10th Africa Movie Academy Awards.[4] A dá orúkọ rẹ̀ ní ìgbà mẹ́ta ní ibi 2014 Nigeria Entertainment Awards. Ìtàn rẹ̀ dá lórí ìgbé ayé ọmọbìnrin adájọ́ kan, tí oníbárà rẹ̀ fẹ́ ṣe ìkọ̀sílẹ̀ nítorí ìbálòpọ̀ pẹ̀lú ẹni kejì rẹ̀ kò tẹ lọ́rùn.[5] Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí a kò lérò ṣẹlẹ̀ , tí ó sì mú oríṣiríṣi nǹkan.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Accident - Xplorenollywood". 27 October 2014.
- ↑ "Chioma Akpotha and Kalu Ikeagwu in Accident". momo.com.ng. Archived from the original on 15 July 2014. Retrieved 22 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Accident set for Release". nollywooduncut.com. Archived from the original on 6 February 2014. Retrieved 22 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Davido, Tiwa, HOAYS, Accident tops nomination list". pulse.ng. 30 May 2014. Archived from the original on 11 June 2017. Retrieved 22 June 2014.
- ↑ "Chioma Akpotha and Kalu Ikeagwu star in Accident". thenet.ng. Archived from the original on 4 July 2014. Retrieved 22 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)