Accountant General of the Federation
Ìrísí
Accountant General of the Federation Nigeria | |
---|---|
Flag of the Federal Republic of Nigeria | |
Accounting | |
Style | Mr. Accountant General |
Member of | Federal Ministry of Finance |
Residence | Treasury House S.L.A Blvd, P.M.B 7015, Garki II, Abuja, FCT, Nigeria |
Appointer | President of Nigeria (Muhammadu Buhari ) |
Iye ìgbà | Four years renewable once |
Constituting instrument | Constitution of Nigeria |
Formation | 1988 |
Website | Official Website |
Accountant General of the Federation jẹ́ olùṣàkóso ti ilé-ìṣura ti orílẹ̀-èdè Federal Republic of Nigeria.[1] Àrẹ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ló máa ń yan olùṣàkóso yìí sípò láti sìn fún ọdún mẹ́rin pẹ̀lú ìṣàkóso tí ìwé-òfin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2] Ọdún 1988 ni wọ́n dá ọ́fíísìì yìí sílẹ̀ lábẹ́ àṣẹ àtúntò àwọn iṣẹ́ ìlú ẹlẹ́kẹ̀kẹtàlélógójì.[3]
Àwọn ojúṣe lábẹ́ òfin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọ́fíísìì yìí ni ojúṣe láti ṣe àkóso gbogbo ètò ìṣúná lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan láti orí àwọn ìwé-ẹ̀rí-owó títí ó fi dé orí owó-sísan ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti láti ri dájú pé àkọọ́lẹ̀ tó péye wà ní gbogbo ẹ̀ka ti ilé-ìṣura ti orílẹ̀-èdè náà. Wọ́n tún ní ojúṣe láti ṣe àmójútó àwọn ìwé-ẹ̀rí owó tó ń wọlé àti àwọn ìnáwó tí orílẹ̀-èdè náà.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Accountant General Of The Federation Hinges On Effective Accounting System". TheNigerianVoice. Retrieved 27 June 2015.
- ↑ Anozim. "Buhari appoints new AGF". The Guardian Nigeria. Retrieved 27 June 2015.
- ↑ "Buhari Appoints Ahmed Idris AGF". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Archived from the original on 27 June 2015. Retrieved 27 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "FG unveils platform to stop revenue theft, diversion". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 30 June 2015. Retrieved 27 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "FG saves N500bn through implementation of Single Treasury Account". Vanguard News. Retrieved 27 June 2015.