Jump to content

Adé Olúfẹkọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adé Olúfẹkọ́
Adé Olúfẹkọ́
Ọjọ́ìbíAdé Olúfẹkọ́
1980
Minneapolis, Minnesota, Amẹ́ríkà
Orílẹ̀-èdèỌmọ Naijiria
Iṣẹ́Tẹknọ́lọ́jì
Ọmọ ìlúSurulere, Lagos

Adé Olúfẹkọ́ (orúkọ ìbí Adé Àbáyọ̀mí Olúfẹkọ́; ọjọ́ìbí, 1980), jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tí ìmọ̀ rẹ̀ jinlẹ̀, eniti Ise re ni imo Eda tayo ni igbimo awon to n pero lori komasi eyi ti o le jeki oro aje lo dede. Adé Olúfẹkọ́ je Olukeko ti o ko eko lori imo Tẹknọ́lọ́jì lati Orile ede Amẹ́ríkà, o tun je oludari ise ati alapero kakiri agbala aiye, omo bibi Ìjẹ̀bú. Ikorita ibiti imo re ni orisirise iriri imo de ni o je ki o da pinnu ni odun 2007 lati da ile ise "wiwo ajọṣepọ" (Visual Collaborative), ibiyi je oju apejo fun awon oniimo eniyan ati isedasile . O je Oga patatata ninu awon ti o seto ilodede idari ni Apejo yi . O tun je konsultanti ni imo ti o to eniyan si ona to pe ni IBM.[1]