Adams Aliyu Ishiaku
Ìrísí
Adams Aliyu Ishiaku | |
---|---|
Member of the Kwara State House of Assembly | |
In office 18 March 2015 – 18 March 2019 | |
Member of the Kwara State House of Assembly from Edu Local Government | |
In office 18 March 2015 – 18 March 2019 | |
Constituency | Edu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹta 1960 Guye-Doko, Edu Local Government Kwara State Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (Nigeria) |
Alma mater | |
Occupation |
|
Adams Aliyu Ishiaku (ojoibi March 27, 1960) je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹjọ to n sójú àgbègbè Edu ni ile ìgbìmọ̀ asofin ìpínlè Kwara nibi to ti ṣíṣe gẹ́gẹ́ bi Alaga ìgbìmọ̀ fun ise àgbè ati oro àlùmọ́ọ́nì. [1] [2] [3]