Adebáyò Faleti

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Adebayo Faleti
Ọjọ́ìbí 26 Oṣù Kejìlá 1930 (1930-12-26) (ọmọ ọdún 88)
Kasmo, Nigeria
Orílẹ̀-èdè Nigerian Nàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nigerian
Alma mater University of Ibadan, Nigeria
Iṣẹ́ Osere, Akewi, Onkowe

Adebayo Akande Faleti (26 December 1930) je omo orilede Naijiria, Akewi, Olukotan, ati elere ori-Itage, ba kan naa ni o tun je ongbufo ede Geesi si ede Yoruba, o si tun je Oniroyin ori Ero asoro-ma-gbesi Radio, Olootu eto ori Telefisan TV, ati Oludasile ile-ise ero Amohun-maworan akoko ni ile Adulawo Africa ti oruko re n je Western Nigeria Television (WNTV).

Adebayo Faleti naa lo se ongbufo orin amuye orilede Naigerian National Anthem lati ede Geesi si ede abinibi Yoruba. Bakan naa ni o tun se ongbifo fun ohun ti Aare orilede Naijiria nigba kan ri lasiko Ologun, iyen Ibrahim Babangida so, pelu ti Aare fidi-he nigba aye Ologun kan ri Chief Ernest Shoneka, nipa lilo ede Yoruba to yanranti. Faleti ti te Iwe-Atumo Dictionary Yoruba ni eyi ti o ni abuda ogidi Yoruba ninu. Adebayo ti gba oniruu-ru ami eye idani lola orisirisi nile yii ati loke Okun pelu.

Awon Ise re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Obìin mẹ́ìndínlógún
 2. N ní ń bẹ́ lọ́ọ̀dẹ̀ẹ Ṣàngó
 3. Ńbi ká sánpá
 4. Ńbi ká yan
 5. LỌyá fi gbọkọ lọ́wọ́ọ gbogbo wọn 5
 6. Ńbii ká sọ̀rọ̀, ká fa kòmóòkun yọ
 7. N la ṣe ń perúu yín léléwì pàtàkì
 8. Fohùn òkè ta ko tìsàlẹ̀ nìkan
 9. Kọ́ là ń pè léwì
 10. Yàtọ̀ sáfiwé ẹlẹ́lọ̀ọ́ àti tààrà 10
 11. Òwe tún ń bẹ rẹrẹrẹ
 12. Wọn a sọ̀rọ̀ tó gbayì létè
 13. Wọn a fi wíwúni lórí lé e
 14. Èyún-ùn nìkan kọ́, kò sẹ́ni tí ò mọ̀yún-ùn
 15. Àní níbii ká máṣà ìṣẹ̀nbáyé 15
 16. Kí gbogbo rẹ̀ tún kú dùn-ún-ùn bí ojú afọ́jú
 17. N la ṣe ń peruu wọn ní baba
 18. Ẹni tó mọ̀Bàdàn tán tó tún mọ Láyípo pẹ̀lú ẹ̀
 19. Tó gbégùn tó gbọ́ wọ́yọ̀wọ́yọ̀
 20. Iwájú lọ̀pá ẹ̀bìtì ó kúkú máá ré sí 20
 21. A kò ní í sàìmáa rí yín báReferences[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control