Jump to content

Adesola Kazeem Adeduntan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adesola Kazeem Adeduntan
Group Managing Director/CEO, First Bank of Nigeria Limited
AsíwájúBisi Onasanya
Director, Chief Financial Officer and Business Manager, Africa Finance Corporation
Senior Vice-President (General Manager) & Chief Financial Officer, Citibank Nigeria Limited
Senior Manager – Financial Services Industry, KPMG Professional Services
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Adeduntan Kazeem Adesola

7 Oṣù Kàrún 1969 (1969-05-07) (ọmọ ọdún 55)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́Mrs Adenike Adeduntan
Àwọn ọmọ3
Alma materUniversity of Ibadan
Cranfield School of Management
ProfessionBanker
Accountant

Adesola Kazeem Adeduntan (a bi ni May 7, 1969) jé omo orílé èdè Nàìjíríà osise ile ifowopamo. O tun je Olusakoso ati Oludari ile ifowopamo First Bank of Nigeria Limited, ati gbogbo ẹka re, o bo ipo yi lati ipo ti o wa tele gege bi Group Chief Financial Officer.[1][2] and an Executive Director with the bank.[3][4] O bẹrẹ ise rẹ pẹlu Afribank Nigeria Plc. ni 1994, lẹhin eyi ti o sise pẹlu KPMG Professional Services, Citibank Nigeria, ati awọn Africa Finance Corporation (AFC) ṣaaju ki o to darapo mo FirstBank ni osu Keje odun 2014.


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Adeduntan, Adesola. "First Bank’s business model has repositioned it for growth". www.vanguardngr.com. Vanguard Newspapers. Retrieved 17 October 2015. 
  2. Adeduntan, Adesola. "Adeduntan, Kumapayi, others set for CFO awards". www.nigeria.shafaqna.com. Retrieved 17 October 2015. 
  3. Adeduntan, Adesola. "First Bank Appoints Adeduntan Executive Director, CFO". www.thisdaylive.com. ThisDay Newspaper. Archived from the original on 25 September 2015. Retrieved 25 September 2015. 
  4. Adeduntan, Adesola. "Company Overview of First Bank of Nigeria Ltd.". www.bloomberg.com. Bloomberg Business. Retrieved 25 September 2015.