Jump to content

Afara Fourth Mainland

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mapu Afara third ati fourth ní ìpinlè Eko
Àwòrán bi afara mainland se gba erukusu atowoda kan.


Afara fourth Mainland jẹ afara to gun to 38 km ti ìjoba ìpínlè Eko, Nàìjíríà se, o so Lagos Island papò mo Itamaga, ni Ikorodu . [1] Afara naa jẹ ọna opopona 2×4, o si ni ònà fún BRT. Ìreti wà pé ouni yo je Afara keji ti o gunjulo ni Afrika. Yó ní plazas toll meta, yó sì gbà Lagos lagoon kojá. [2] ìjọba Sẹnetọ Bola Ahmed Tinubu, Gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní ìpínlẹ̀ Èkó ló mú àbá afara náà wá. A gbero lati bẹrẹ kíkó rè ni ọdun 2017, ọdun aadota lẹhin ti a da ipinlẹ naa ati ọdun merindinlogbon lẹhin tí a kó afara third mainland, nireti pe yoo pari ni ọdun 2019,[3] . Wón ni kíkó rè ma gbà iye owo 844 bilionu ni isuna 2017.[4][5]. Ni oṣu kẹsan ọdun 2020, Ijọba ipinlẹ Eko dabtí o jé owo miiran ti $2.2 million fun kíkó rè. Awọn ile 800 ni a nireti lati wó. [6][7][8] Ni Oṣu Kẹrin ọdun 2021, awọn ilé-isé mefa ni o so pé àwon nifesi kíkó afara naa, isé tí owo kíkó rè lé ní 2.5 billion USD. Ni Oṣu Kejila, wón ni eni ti wón bá mú yo di mímò.[9]

Ni January 2022, Gomina Ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu, fi to gbogbo eniyan leti pe awọn ile-iṣẹ mẹta ti de ipele ikẹhin, ati pe wọn yoo gba adehun ni Oṣu Kẹta 2022.

  1. "Lagos assembly ll support delivery of fourth mainland bridge". https://m.guardian.ng/news/lagos-assembly-ll-support-delivery-of-fourth-mainland-bridge. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. Nwannekanma, Bertram (September 29, 2020). "800 houses for demolition as Lagos budgets $2.2b of 4th Mainland Bridge". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on September 11, 2022. Retrieved September 12, 2022. 
  3. "LASG to begin construction of 4th Mainland Bridge this year – Commissioner". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-03. 
  4. "Construction of Fourth Mainland Bridge to start this year". TheGuardian. NAN. Archived from the original on 5 November 2017. Retrieved 4 November 2017. 
  5. "Lagos: N844billion 4th Mainland Bridge project up in 2019". TheSun. Punch. Retrieved 4 November 2017. 
  6. "You are being redirected...". businessday.ng. Retrieved 2021-01-03. 
  7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  8. "795 houses to go for Lagos Fourth Mainland Bridge | The Nation". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-04. Retrieved 2021-01-03. 
  9. "Lagos says Fourth Mainland Bridge contract with funding ready in December 2021 - Nairametrics" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-28. Retrieved 2022-01-15.