Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Abẹ́òkúta
Ìrísí
Abeokuta North | |
---|---|
Coordinates: 7°12′N 3°12′E / 7.200°N 3.200°ECoordinates: 7°12′N 3°12′E / 7.200°N 3.200°E | |
Country | Nigeria |
State | Ogun State |
Government | |
• Local Government Chairman | Adebayo Ayorinde (APC) |
Area | |
• Total | 808 km2 (312 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 201,329 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 110 |
ISO 3166 code | NG.OG.AN |
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Abẹ́òkúta jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rè wà ní ìlú Akomoje, lágbèbè Abeokuta. Ó ní ìwọ̀ ilẹ̀ tó tóbí tó 808 km2 àti èrò ènìyàn tó tó bíi 201,329, lásìkò ìkarí ti ọdún 2006.
Ní agbègbè yìí, a ní Oyan Dam, tó jẹ́ orísun omi pàtàkì fún Ìpínlẹ̀ Èkó àti Abeokuta. Àwọn ará-ìlú sì gbẹ́kẹ̀le fún ẹja pípa àti ìpèsè omi.[1]
Kóòdù ìfìwéránṣe ti agbègbè náà ni 110.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ O. P. Akinwale; G. C. Oliveira; M. B. Ajayi; D. O. Akande; S. Oyebadejo; K. C. Okereke. "Squamous Cell Abnormalities in Exfoliated Cells from the Urine of Schistosoma haematobium-Infected Adults in a Rural Fishing Community in Nigeria". World Health & Population, 10(1) 2008: 18-22. Retrieved 2010-05-22. Unknown parameter
|name-list-style=
ignored (help) - ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)