Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gbọ̀ngàn Ibarapa
Appearance
Ibarapa Central | |
---|---|
Igbo-Ora High School I located directly opposite Oyo State College if Agriculture in Igbo-Ora Ibarapa Central local Government, Oyo state. | |
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Adedoyin Oloyede Adeoye (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gbọ̀ngàn Ibarapa jẹ́ ọ̀kan lára àọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gbọ̀ngàn Ibarapa jẹ́ àpapọ̀ ìlú Igbo-Ora àti Idere. Olú-ìlú náà wà ní Igbo-Ora.
Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 440 km2 àti iye ènìyàn tó tó 102,979 ní ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006. Ní ọdún 2018 iye àwọn ènìyàn di 322,189. Àwọn Yorùbá ló pọ̀ jù ní ìlú náà.
Kóòdù ìfìwérá́nṣẹ́ ìlú náà ni 201.[1]
Àwon ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)