Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ipokia
Àyọkà yi ni opo oran. Jọwọ ran lowolati ṣe àtúnṣe tabi soro nipa isoro re lori ọ̀rọ̀. (Learn how and when to remove these template messages)
|
Ipokia | |
---|---|
LGA and town | |
Coordinates: 6°32′N 2°51′E / 6.533°N 2.850°ECoordinates: 6°32′N 2°51′E / 6.533°N 2.850°E | |
Country | Nigeria |
State | Ogun State |
Government | |
• Local Government Chairman | Wale Agbetokun (APC) |
Area | |
• Total | 629 km2 (243 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 150,426 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 111 |
ISO 3166 code | NG.OG.IP |
Ipokia je olu-ilu Anago. Ipokia si je okan lara awon ijoba ibile ni Ipinle Ogun ni odun 1996. Awon ilu miiran to wa nibe ni Agosasa, Idiroko, Oniro, Ita Egbe,Ihunbo, Aseko, Maun, Kọkọ, Ropo, Alaari, Tube, Ilashe, Ifonyintedo, Madoga, Ijofin ati Tongeji t6°32′00″N 2°51′00″E / 6.53333°N 2.85000°E.
O ní iwon agbegbe to to 629 km2 Ari iye eniyan to to 150,426 nigba ika-ori ni odun 2016.
Minerals/Natural resources
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ipokia town has large deposits of Kaolin and Red clay. The vast fertile land is available for Agriculture. It is equally rich in soft sand used in the construction industry. Large and commercial deposit of crude oil was discovered in Tongeji Island (a town under Ipokia) by the Federal government of Nigeria.The drilling will take effect soonest by the government and this will provide more revenue for the country and job creation for the beneficial of the indigene .Establishment of oil refinery will soon take effect.
Tourism
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A mega tourist city and sea institute was being developed at Whekan Island by the team of Queens Atlantic Resorts Inc., of Las Vegas, Nevada U.S.A. there is room for Boat Regatta, Canoeing and fishing along the Badagry creek. Although the project has since stop due to issue not known. Tongeji Island is a holiday haven with its impressive water front and breathtaking scenery, the island is a beauty to behold. Onigbaale Forest is equally a major tourist attraction. It was reported that the 1st Onigbaale of Ipokia precisely disappeared there and has since not been seen.
Famous foods
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ipokia cuisine is rich with numerous delicacies original to the Town. Listed below are some of the foods peculiar to the towns and their recipe;
- Gbangba-grinded and farmented corn mill
- Imoyo - Pepper, tomato, locust beans, onion, coconut oil, smoked fish, table salt
- Gbon-npete soup - Maize powder, pepper,
meat, oil, salt.
- Atakere - Beans, Pepper, oil, salt.
- Abodo - cassava, salt
- Benju - Cassava, Coconut, salt .
- Ajungun - Maize, Cassava, Oil, Salt &
pepper
- Adalu - Maize, Beans, Salt, Pepper & Oil.
- Atutu(Tutu) - Maize Powder, Beans, Salt, Oil and
Pepper
- Atomboro - Beans, Salt, Pepper and oil.
- Epete-Ewa - Beans Powder, Palm Seed, Salt
and Pepper
- Idoki - Smoke, Fried or Boiled Sweet Potatoes.
- Tuwo(Oka) - Corn Flour
- Eko(Akamu) - Corn
- Asepo - Okra, Smoked Fish, Onion Pepper, Salt, Oil
Awon ede
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ede ti won maa n so ju ni Anago, eyi to je okan lara awon eka-ede Yoruba.
Awon eka-ede yooku ni; Egun, Eyo ati ede Geesi, to je ede ajumoso ni ile Naijiria.
Iroyin nipa ifiweranse
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Koodu ifiweranse ilu yii ni 111.[1]
Ilu ati ileto ni Ipokia
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ijofin
- Agada
- Agbologun
- Agosasa
- Ajise
- Ajegunle
- Aseko
- Ayetoro
- Gaun
- Ibatefin
- Idiroko
- Ifonyintedo
- Igbeko
- Igbodoroju
- Igborodo
- Igude
- Igunnu
- Iguu
- Ihunbo
- Ikate (Igate)
- Ilase
- Ipokia
- Ita Egbe
- Ita Onimowo
- Iwuku
- Iyasi
- Maun
- Madoga
- Odepata
- Oniro
- Tongeji
- Tube
- Whekan
- Itafa
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ipokia wa ni Naijiria
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |