Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Babura

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Babura)

Agbegbe Ijoba Ibile Babura je ijoba ibile ni Ipinle Jigawa ni Nigeria.

Babura jẹ Local Government Area ni Ariwa Jigawa State, Nigeria. O Pin ààlà kannáà pẹlu ijoba ibile Baure ti ìlú Katsina state lati Ariwa , Kazaure lati ìwọ̀ oòrùn Sule Tankarkar láti ila-oorun ati ìjọba ibile Danbattaof ti ìlú Kano lati guusu. Olú ilese je ìlú Babura. Adari agbegbe lowo lọwọ ti Babura ti ọ ti jẹ oyè Sarkin Bai of Ringim, Ringim Emirate Council, Alhaji Muhammad Nata’ala Mustapha (Councillor & King Maker) ti wà lórí oyè láti oṣù kẹrin ọdún 2019 lẹyìn ikú àbúrò rẹ̀ Alhaji Hadi Mustapha Musa of the Bani Ya Musa clan.

O jẹ agbegbe 992 km2 pẹlu awọn eniyan inú rẹ̀ 208,101 at the 2006 census.

The postal code of the area is 732.[1]iItokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)