Jump to content

Ahmed Mohamed Mohamoud

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ahmed Mohamed Mohamoud
احمد محمد محمود
Mohamoud in 2011
4th President of Somaliland
In office
27 July 2010 – 13 December 2017
Vice PresidentAbdirahman Saylici
AsíwájúDahir Riyale Kahin
Arọ́pòMuse Bihi Abdi
Chairman of Peace, Unity, and Development Party
In office
2002–2010
AsíwájúPosition established
Arọ́pòMuse Bihi Abdi
9th Minister of Finance
In office
1997 – 1999[1]
ÀàrẹMuhammad Haji Ibrahim Egal
AsíwájúYusuf Ainab Muse
Arọ́pòMohamed Said Mohamed
Member of the Somaliland House of Representatives
In office
1993–1996
Chairman of the Somali National Movement
In office
9 August 1984[2] – April 1990
AsíwájúColonel Abdiqadir Kosar Abdi
Arọ́pòAbdirahman Ahmed Ali Tuur
Minister of Planning and International Cooperation of Somalia
In office
1965–1973
ÀàrẹMohamed Siad Barre
Minister of Commerce of Somalia
In office
1973–1978
ÀàrẹMohamed Siad Barre
In office
1980–1982
ÀàrẹMohamed Siad Barre
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1938 (ọmọ ọdún 85–86)
Burao, British Somaliland (now Somaliland)
AráàlúSomalilander
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeace, Unity, and Development Party
(Àwọn) olólùfẹ́Amina Weris Sheikh-Mohamed Jirde
Alma materSOS Sheikh Secondary School
University of Manchester
Signature

Ahmed Mohamed Mohamoud "Silanyo" (Àdàkọ:Lang-so, Lárúbáwá: احمد محمد محمود سيلانيو‎; tí a bí ní ọdún 1938) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Somalila, òun ni ààrẹ tí ó dárí Somalia láàrin ọdún 2010 sí 2017. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ mínísítà fún ètò ọrọ̀ ajé Somali Republic, ó sì ti di àwọn ipò mìíràn mú ní ìjọba. Oun ní o jẹ́ alága Somali National Movement nígbà àwọn ọdún 1980s.[3]

A yàn án gẹ́gẹ́ bí ààrẹ orílẹ̀ èdè Somalia ní ọdún 2010.[4] Ahmed ní ààrẹ kẹrin láti gun orí àléfà ìjọba orílẹ̀ èdè Somalia.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ministry of Finance of Somaliland - Former Ministers". Ministry of Finance (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12. 
  2. 37. Somalia/Somaliland (1960-present). https://uca.edu/politicalscience/dadm-project/sub-saharan-africa-region/somaliasomaliland-1960-present/. 
  3. "Somaliland Election Results Released: Siilaanyo Is New President". Bridge Business Magazine. 3 August 2010. 
  4. "Opposition leader elected Somaliland president". AFP. https://www.google.com/hostednews/afp/article/ALeqM5j8hma5FaM4Jn8UUVlRwwK18hpStQ.