Jump to content

Muse Bihi Abdi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Muse Bihi Abdi
موسى بيحي عبدي
Official portrait, 2017
5th President of Somaliland
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
13 December 2017
Vice PresidentAbdirahman Saylici
AsíwájúAhmed Mohamed Mohamoud
Chairman of Peace, Unity, and Development Party
In office
31 December 2010 – 21 August 2023 [1]
AsíwájúAhmed Mohamed Mohamoud
Arọ́pòshuaib hassan adan
Minister of Interior
In office
1993–1995
ÀàrẹMuhammad Haji Ibrahim Egal
AsíwájúSuleiman Mohamoud Adan
Arọ́pòAhmed Jaambiir Suldan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1948 (ọmọ ọdún 75–76)
Hargeisa, British Somaliland
Ọmọorílẹ̀-èdèSomalilander
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeace, Unity, and Development Party
(Àwọn) olólùfẹ́Zahra Abdilahi Absia
Roda Ahmed Omar
Àwọn ọmọ7
Alma materUniversity of Hargeisa
SignatureMuse Bihi Abdi stylized autograph, in ink

Musa Bihi Abdi (Àdàkọ:Lang-so, Lárúbáwá: موسى بيحي عبدي‎; tí a bí ní ọjọ́ 1948)[2] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Somalia, òun ni ààre orílẹ̀ èdè Somalia láti oṣù kẹwàá ọdún 2017. Nígbà 1970s, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi awa ọkọ̀ ojú òfuurufú fún àwọn ọmọ ológun òfuurufú Somalia lábé ìdarí Siad Barre. Ní ọdún 2010, a yan Bihi sípò alága ẹgbẹ́ òṣèlú Kulmiye ti Republic of Somaliland. Ní oṣù kọkànlá ọdún 2015, a tún yan Bihi gẹ́gẹ́ bi ẹni tí yóò du ipò ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú náà.[3][4]

Ní ọjọ́ kànlélógún oṣù kọkànlá ọdún 2017, a kéde Muse Bihi gẹ́gẹ́ bi ẹni tó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ orílẹ̀ èdè Somalia ti ọdún 2017. Ó di ààrẹ Somalia ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Kejìlá ọdún 2017.[5][6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Burco: Xiabiga Kulmiye oo mar kale musharax Madaxweyne u doortey Biixi". 21 August 2023. 
  2. Olad, Mohamed (21 November 2017). "Somaliland Ruling Party Candidate Bihi Wins Election". Voanews.com. Retrieved 8 December 2017. 
  3. "Somalia: Wrangle splits Somaliland Ruling Party as President Siilaanyo seeks re-election". 26 May 2014. http://allafrica.com/stories/201405270406.html. 
  4. "Muse Bihi and Saylici Elected as Kulmiye's Presidential Candidate". 11 November 2015. Archived from the original on 28 January 2016. https://web.archive.org/web/20160128022439/http://galgalanews.com/articles/182/Somaliland-Muse-Bihi-and-Saylici-Elected-as-Kulmiyes-Presidential-Candidate. 
  5. Olad, Mohamed. "Somaliland Ruling Party Candidate Bihi Wins Election" (in en). VOA. https://www.voanews.com/a/somaliland-ruling-party-candidate-bihi-wins-election/4128446.html. 
  6. "PRESIDENT BIHI REPLACES HEADS OF MULTIPLE FOREIGN MISSIONS". Somaliland Chronicle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 November 2019. Retrieved 14 March 2020.