Jump to content

Aishat Abubakar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aisha Abubukar(tí a bí ní 20 July, 1966) jé olósèlú ní orílè-ede Nàìjirià [1], Ààre Muhammadu Buhari yàn gẹ́gẹ́ bí mínísítà fún ilé-iṣẹ́ , okòwò, ati investment ní ọdùn 2015. Nì ọdùn 2018, Ààre Muhammadu Buhari tún yàn àn gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún òrò obínrin àti ìdàgbà-sókè àwùjọ. [2]

Aisha Abubakar
Minister of State for Industry, Trade and Investment
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2015
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20 July 1966
Sokoto State
EducationQueens College
University of Warwick
University of Leeds

Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kó rè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abí Hajiya Aishat Abubakar ní inú ogúnjọ́ oṣù keje, ọdún 1966 sí ìlú Dogondaji ní Ìpínlẹ̀ Sókótó. Ó jẹ́ omo mínísítà fún ètò owó tẹ́lẹ̀ ri, Abubukar Alhaji [3]. Ó lọ sí ilé-ìwé sẹ́kọ́ndìrì rè ní ilé-ẹ̀kọ́ Queens College ti ìpínlè Èkó lá̀árín ọdún 1978-1984, ó gba ìwé ẹrí dìgírì rè ní Yunifásitì ti Warwick, ó sì tún tẹ̀ síwájú láti gba ìwe ẹ̀rí Master degree ní Yunifásitì ti Leeds. [4]

  1. "Minister of State for Industry, Trade and Investment, Hajiya Aisha Abubakar paid Sallah homage to Acting President Yemi Osinbajo". Blueprint Newspapers Limited. 2017-07-14. Retrieved 2022-03-28. 
  2. "Buhari appoints Hajiya Aisha Abubakar as Minister Women Affairs and Social Development". The Sun Nigeria. 2018-09-30. Retrieved 2022-03-28. 
  3. "Meet the six women nominated for ministerial positions by Buhari". Nigerian News. Latest Nigeria News. Your online Nigerian Newspaper. 2015-10-15. Retrieved 2022-03-28. 
  4. Nwabufo, Fredrick (2015-10-19). "Aisha Abubakar ‘competent’ to be minister". TheCable. Retrieved 2022-03-28.