Ajibola Muraina
Ìrísí
Ajibola Saubana Muraina je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. O je ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣòfin to n sójú àgbègbè Ibarapa Central / Ibarapa North ti Ìpínlẹ̀ Oyo ni ile igbimo aṣòfin agba kesan-an. [1] [2] [3]