Jump to content

Ali Nuhu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ali nuhu)
Ali Nuhu
ọmọnìyàn
ẹ̀ka òwòfilm industry, Ètò amóhùn máwòrán ti Nàíjíríà Àtúnṣe
ẹ̀yàakọ Àtúnṣe
country of citizenshipNàìjíríà Àtúnṣe
name in native languageAli Nuhu Mohammed, Ali nuhu Àtúnṣe
orúkọ àbísọAli Nuhu Mohammed Àtúnṣe
orúkọ àfúnniAli Àtúnṣe
ọjó ìbí15 Oṣù Ẹ̀rẹ̀nà 1974 Àtúnṣe
ìlú ìbíMaiduguri Àtúnṣe
native languageÈdè Haúsá, Waja Àtúnṣe
languages spoken, written or signedgẹ̀ẹ́sì, Èdè Haúsá, Èdè Lárúbáwá, Nigerian Pidgin Àtúnṣe
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀òṣèré, film director, olóòtú eré, screenwriter Àtúnṣe
ẹ̀kà iṣẹ́theater arts Àtúnṣe
kẹ́ẹ̀kọ́ níYunifásítì ìlú Jos Àtúnṣe
academic degreebachelor's degree, Bachelor of Arts Àtúnṣe
residenceKánò Àtúnṣe
work period (start)1999 Àtúnṣe
religion or worldviewÌmàle Àtúnṣe
eye colorblack, brown Àtúnṣe
hair colorIrun dúdú Àtúnṣe
official websitehttp://www.alinuhu.net Àtúnṣe
personal pronounL485 Àtúnṣe
Àwòrán Ali Nuhu níbi ayeye AMVCA 2020

Ali Nuhu Mohammed (táabì ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, ọdún 1974) jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà àti olùdarí.[1]Ó má ń ṣe ère Haúsá àti ère Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn òní ròyìn má ń pè ní "king of kannywood" tàbí "sarki". Kannywood ni orúkọ ilé ìṣe fímù Hausa.[2] Nuhu ti kópa nínú àwọn ère Nollywood Àti Kannywood tí ó tó Ẹ̀dẹ́gbẹ́ta filmu. [3]

Nuhu jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Maiduguri, Borno State ní Àríwá Ìwọ̀ Òrùn. Bàbá rẹ̀, Nuhu Poloma jẹ́ ọmọ Ìlú Balanga ni ìpínlẹ̀ Gombe àti Ìyá rẹ̀, Fátima Karderam Digema jẹ́ ọmọ ìjọba àgbègbè Bama ni ìpínlè Borno.[4]Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Jos àti Kano. Ó lọ sí Fáṣítì Jos, níbi tí ó ti gba Oyè ẹ̀kọ́ ní Arts.Ó ṣe Ẹ̀sìn orílè èdè ni Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ó padà lọ sí University of Southern California fun Ẹ̀kọ́ nínu ṣíṣe fíìmù àti àwọn ọ̀nà sinimá.[5]

Àkójọ̀pó Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ali Nuhu returns to school". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 13 October 2017.
  2. "An karrama Ali Nuhu da Adam Zango a London". bbc.com/hausa. BBC. Retrieved 13 October 2017.
  3. "Ali Nuhu, Adam Zango, others win awards in London". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 13 October 2017.
  4. https://www.voahausa.com/a/a-39-2005-08-06-voa1-91733284/1370189.html
  5. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-10-10. Retrieved 2020-10-09.