Jump to content

Ambrose Campbell

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ambrose Campbell
Orúkọ àbísọỌládipúpọ̀ Adékọ̀yà Campbell
Ọjọ́ìbí(1919-08-19)19 Oṣù Kẹjọ 1919
Èkó, Nigeria
Aláìsí22 June 2006(2006-06-22) (ọmọ ọdún 86)
Ìlú Plymouth, orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì
Irú orinOrin afẹ́, olórin Jùjú, jazz, rock, etc.
Occupation(s)Akọrin, bandleader, guitarist
InstrumentsAtajìǹtá, percussion
Years active1946–1990s
LabelsMelodisc, Columbia
Associated actsLes Ballets Nègres, Leon Russell, Willie Nelson, Ronnie Scott, Tubby Hayes and Phil Seamen.

Ambrose Campbell tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Ọládipúpọ̀ Adékọ̀yà Campbell tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1919, ó sìn kú lọ́jọ́ méjìlélógún oṣù kẹfà ọdún 2006 (19 August 1919 – 22 June 2006) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin àti adarí orin ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni wọ́n gbà pé ó jẹ́ olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ olórin àwọn adúláwò àkọ́kọ́ tí wọ́n ń pè ní the West African Rhythm Brothers lórílẹ̀-èdè Bìrìtìkó ní nǹkan bí ọdún 1940, bẹ́ẹ̀ náà gbajúgbajà olórin Fẹlá Aníkúlápó Kútì náà gbà pé òun ni bàbá àwọn olórin ìgbàlódé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó ṣiṣẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pọ̀ àwọn olorin Jazz lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì ní nǹkan bí ọdún 1950, pàápàá jù lọ, Leon Russell tí ó bá ṣeré kiri, tí ó sìn tún bá ṣe àwo-orin pọ̀ lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, níbi tí ó gbé fún ọgbọ̀n ọdún gbáko.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ankeny, Jason. "Ambrose Campbell". Allmusic.com. Retrieved 5 September 2013.