Jump to content

Amina Oyiza Bello

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amina Oyiza Bello
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kẹrin 1978 (1978-04-02) (ọmọ ọdún 46)
Kuroko, Ìpínlẹ̀ Kogi
Orílẹ̀-èdèỌmọ Nàìjíríà
Ẹ̀kọ́University of Leicester
Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University
Olólùfẹ́Yahaya Bello

Amina Oyiza Bello, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún (2 April 1978) jẹ́ agbẹjọ́rò, afowóṣàánú àti ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kogi, Yahaya Bello, Kogi State Governor. Òun ni Alága àti olùdásílẹ̀ Fairplus International, Hayat Foundation, bẹ́ẹ̀ náà lọ jẹ́ pàràkòyí oníṣòwò. [1][2]

Amina kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin láti Obafemi Awolowo UniversityIlé-ìfẹ́Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Nàìjíríà.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]