Ijasirere asailaju Egipti ayeijoun je be nitori agbara re lati le gbe pelu awon isele Ifonofoji Odo Nilo. Agbara asotele ati ikojanu ibomirin ile olora inu afonifoji fa opo eso ogbin wa, eyi lo si mu idagbasoke awujo ati asa wa. Pelu opo ohun amulo o se ese fun ijoba lati segbowo imulo awon alumoni to wa ni afonifoji Nilo ati awon agbegbe ashale to yika, atetebere idagbasoke sistemu ikoole fun ra ara won, igbajo ikole akojopo ati awon iseowo iseagbe, idunadura pelu awon agbegbe ayika, ati ise ologun to fe segun awon ota okere to si le fi agbara Egypti han. Lati sakoso awon agbese wonyi ni awon akowe, olori esin, ati awo aseamojuto labe ijanu Farao, eni to ridaju pe awon eniyan ara Egipti wa lokan labe sistemu awon igbagbo esin.[4][5]
Ninu awon opo oriire awon ara Egipti ayeijoun ni okuta fifo, ile wiwon ati awon ona ikole to fa kiko awon piramidi gbangba, tempili, ati obeliski; sistemu mathimatiki, sistemu iwosan to sise ati to se e mulo, awon sistemu ibomirin ati ona ida iseagbe, awon oko-ojuomi akoko,[6]amo fiyansi Egypti ati iseoroiseona digi (gilasi), iru isemookomooka tuntun, ati adehun alafia atetejulo ti a mo.[7] Egypt left a lasting legacy. Its art and architecture were widely copied, and its antiquities carried off to far corners of the world. Its monumental ruins have inspired the imaginations of travellers and writers for centuries. A new-found respect for antiquities and excavations in the early modern period led to the scientific investigation of Egyptian civilization and a greater appreciation of its cultural legacy.[8]