Àngúíllà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Anguilla)
Anguilla

Motto: "Strength and Endurance"
Orin ìyìn: God Save the Queen
National song: God Bless Anguilla 1
Location of Àngúíllà
OlùìlúThe Valley
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
90.1% West African, 4.6% Multiracial, 3.7% European, 1.5% other[1]
Orúkọ aráàlúAnguillian
ÌjọbaBritish Overseas Territory
• Monarch
HM Queen Elizabeth II
• Governor
William Alistair Harrison
Ìdásílẹ̀
1980
Ìtóbi
• Total
91 km2 (35 sq mi) (220th)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• 2006 estimate
13,600[2] (212th)
• Ìdìmọ́ra
132/km2 (341.9/sq mi) (n/a)
GDP (PPP)2004 estimate
• Total
$108.9 million
• Per capita
$8,800
OwónínáEast Caribbean dollar (XCD)
Ibi àkókòUTC-4
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù+1-264
ISO 3166 codeAI
Internet TLD.ai
  1. "National Song of Anguilla". Official Website of the Government of Anguilla. Retrieved 12 October 2005. 

Coordinates: 18°13′14″N 63°4′7″W / 18.22056°N 63.06861°W / 18.22056; -63.06861 Anguilla Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tó wa ní Anguilla jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje àti ọgọ́rùn-ún (7,100). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀. Púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ibẹ̀ ni wọ́n ń sọ èdè Kirió tí wọ́n gbé ka èdè Gẹ̀ẹ́sì (English based Creole). Kirió yìí ni ó wọ́pọ̀ jù ní Áńtílẹ́ẹ̀sì (Lesser Antilles)Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Anguilla World Fact Book". Archived from the original on 2020-04-07. Retrieved 2009-10-24. 
  2. Country Profile: Anguilla, Travel & Living Abroad, Foreign & Commonwealth Office